Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
score
float32
1.04
1.24
Oromo
stringlengths
10
497
Yoruba
stringlengths
7
500
1.241526
Isaan keessaa tokkoyyuu fedhii Abbaa keessanii malee lafa hin buutu.
Ati pe ko si ọkan ninu wọn ti yoo ṣubu lulẹ laisi Baba rẹ.
1.233961
'Bara duriitti Waaqayyo si'a baay'ee karaa gara garaatiin raajotaan abboota keenyatti dubbateera.
ỌLỌRUN, ẹni, ni igba pupọ̀ ati li onirũru ọna, ti o ti ipa awọn woli ba awọn baba sọ̀rọ nigbãni.
1.232775
hojjattoota erguuf kadhadhaa."
Nítorí náà ẹ bẹ Oluwa ìkórè kí ó rán àwọn òṣìṣẹ́ sí ibi ìkórè rẹ̀.
1.223164
8 Taladanu kama iman kan idiin yeedhaya.
8 Iyipada yi kò ti ọdọ ẹniti o pè nyin wá.
1.219934
Walitti kan toltan, garaas kan waliif laaftan ta'aa; akkuma Waaqayyo karaa Kiristos cubbuu keessan isiniif dhiise, isinis akkasuma waliif dhiisaa.
Ẹ jẹ oninuure ati aanu si ara yin, ẹ dariji ara yin, gẹgẹ bi ninu Kristi Ọlọrun ti dariji yin.
1.218528
Waqayyoof Waanti Hin Danda'amne Hin Jiru "
Nítorí kò sí ohun tí ó ṣòro fún Ọlọrun.
1.215418
Walitti kan toltan, garaas kan waliif laaftan ta'aa; akkuma Waaqayyo karaa Kiristos cubbuu keessan isiniif dhiise, isinis akkasuma waliif dhiisaa.
Ẹ máa ṣoore fún ara yín, ẹ ní ojú àánú; kí ẹ sì máa dáríjì ara yín, gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti dáríjì yín nípasẹ̀ Kristi.
1.211541
"Simbirroonni lama beessee tokkotti gurguramuu mitii?
Kì í ha ṣe ológoṣẹ́ méjì ni a ń tà ní ẹyọ owó kan?
1.21049
47Sa̱a̱ jnaan Salomón juu sꞌaa wꞌaaꞌñeen cwentaaꞌ Tyꞌo̱o̱tsꞌom.
Ṣugbọn Solomoni ni ó kọ́ ilé fún un.
1.209959
"Ammas harka Waaqayyo isa isin jabeessu, dubbii ayyaana isaa isa qulqulloota isaa hunduma gidduutti dhaala isiniif kennuu dandda'uttis isin nan kennadha.
"Nisinsinyii, mo fi yín lé Ọlọrun lọ́wọ́ ati ọ̀rọ̀ oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀ tí ó lè mu yín dàgbà, tí ó sì lè fun yín ní ogún pẹlu gbogbo àwọn tí a ti sọ di mímọ́.
1.20792
Dubbiin kee miila kootiif ibsaa dha, daandii koo irrattis in ifa.
Ọrọ rẹ jẹ fitila si ẹsẹ mi, ati imọlẹ si ọna mi.
1.207305
jira; isin garuu maaliif waldaa Waaqayyoo irratti ol of qabdu ree?"
Ẽṣe ti iwọ gbe ara loke awọn enia Oluwa?"
1.20646
11:33-34:- "Badhaadhummaan araara Waaqayyoo hammam guddata!
Ìwé Romu 11:33 polongo wípé, "Ah! ìjìnlẹ̀ ọ̀rọ̀ àti ọgbọ́n àti ìmọ̀ Ọlọ́run!
1.204524
"Namoonni torbaatamii lamaan sunis gammachuun deebi'anii, "Yaa Gooftaa, jinniiwwanilleen maqaa keetiin nuu ajajamaniiru" jedhan.
Àwọn àádọ́rin náà sì fi ayọ̀ padà, wípé, Olúwa , àwọn ẹ̀mí èṣù tilẹ̀ foríbalẹ̀ fún wa lí orúkọ rẹ.
1.203679
Jireenni nyaata hin caaluu? nafnis
Ṣe igbesi aye ko ju ounjẹ lọ, ara si ju aṣọ lọ?
1.202276
Inka akka nti ra nen ni lanja ni ani andhi.
Ṣugbọn mo ní igbẹkẹle ninu Oluwa pé èmi fúnra mi yóo wá láìpẹ́.
1.201635
Israa'iilow, i maqal oo anna waan kuu markhaati furi doonaa,
Gbọ, Israeli, emi o si jẹri fun o.
1.201005
"Manni Isiraa'el garuu, 'karaan Waaqayyoo qajeelaa miti!' jedhu.
Sibẹsibẹ àwọn ọmọ Israẹli ń wí pé, 'Ọ̀nà OLUWA kò tọ́.
1.201
32 Inni garuu deebisee, "Ani nyaata isin hin beekne kanan nyaadhu qaba" isaaniin jedhe.
32 Ṣugbọn o wi fun wọn pe, emi li onjẹ lati jẹ, ti ẹnyin kò mọ̀.
1.195362
Eeyyee bara jireenya koo hundumatti gaarummaan kee fi arjummaan kee ana duuka in bu'u; guyyoota kana hundumaafis mana Waaqayyoo keessa nan jiraadha."
Nitotọ, ire ati ãnu ni yio ma tọ̀ mi lẹhin li ọjọ aiye mi gbogbo; emi o si ma gbe inu ile Oluwa lailai
1.194201
Yesus immoo gara isaanii ilaalee, "namootaaf hin danda'amu, Waaqayyoof garuu akkas miti; Waaqayyoof waanti hundinuu ni danda'ama" jedhe
Jesu wò wọ́n lójú, ó sọ fún wọn pé, "Èyí kò ṣeéṣe fún eniyan; ṣugbọn ohun gbogbo ni ó ṣeéṣe fún Ọlọrun."
1.192865
Isin keessaa nama attamiitu ilmi isaa buddeena yoo isa kadhate, dhagaa kennaafii ree?
Ta ni ninu yín, tí ọmọ rẹ̀ bá bèèrè àkàrà, tí ó jẹ́ fún un ní òkúta?
1.192686
Waaqayyo filannoo siif kenneera.
Ọlọ́run fún ọ láàyè láti yàn.
1.192396
4Eegaa akka gammachuun teenya guutamtuuf jecha, kana hundumaa isiniif barreeysina.
À ń kọ àwọn nǹkan wọnyi si yín kí ayọ̀ wa lè kún.
1.190591
haaraa fi lafa haaraa in uuma,
Bẹẹni yóò rí pẹ̀lú ọrun tuntun àti ayé tuntun.
1.189887
Yasaloona ayyana yawmu alddeeni;
Ṣugbọn Solomoni ni ó kọ́ ilé fún un.
1.189254
24 Waaqayyo hafuura; warri isaaf saga danis hafuuraa fi dhugaadhaan isaaf sagaduun in ta'aaf" ittiin jedhe*.
24 Ẹmí li Ọlọrun: awọn ti o ba foribalẹ ki o mã sìn ni ẹmí ati otitọ.
1.188865
Imisa sano ayuu noolaa Yooxanaa Rasuulku?
Ọdun melo ni Johanu Aposteli gbe?
1.188757
"Obboleettiiwwan isaa, isaan nu wajjin hin tureeyii?
Àwọn arábìnrin rẹ̀ gbogbo ha kọ́ ni ó ń bá wa gbé níhìn-ín yìí?"
1.187588
"Yihowaatti Amanami, Wanta Gaarii Taʼes Hojjedhu"
"Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, Kí O sì Máa Ṣe Rere"
1.187211
Unakku Okeennaa Moonu Peerum Seenthu Pannuvom.
"Kí ó lè dára fún ọ, ati kí o lè pẹ́ lórí ilẹ̀ náà.
1.185595
Raajonnis du'anii ru, ati eenyu of seeta?" jedhaniin*.
Àwọn wòlíì sì kú: ta ni ìwọ ń fi ara rẹ pè?"
1.185463
Abboommonni kurnan isaan kamiidha?
Kini Awọn Òfin Mẹwàá?
1.184726
Miyay idiin gargaari karaan, mase u gargaari karaan nafahooda?"
(73) Mase idin Anfaci ama idin Dhibi.
1.18412
dah! ama kweli uuuwiiii
tabi ki RuNaL,
1.182881
Inni akkas jedha, ilaala, "Samiifi lafti ni darbu, jechootni koo garuu hin darban.
Ó ní, wò ó, "Ọ̀run àti ayé yóò kọjá lọ, Sùgbọ́n àwọn ọ̀rọ̀ mi kí yóò kọjá
1.182309
(trg) ="5"> Ibsi gara biraan yoo kenname malee , caqasawwan barreeffama kana keessatti argaman Kitaaba Qulqulluu Hiika Addunyaa Haaraa Maatewos - Mulʼata fi Macaafa Qulqulluu afaan Oromoo bara 1997 tti maxxanfame keessaa kan fudhatamani dha .
(trg) ="5"> Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀ , inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun , la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò .
1.181989
Kanaaf, Waaqayyo magaalaa waan isaaniif qopheesseef, Waaqa isaanii jedhamee waamamuutti hin qaanaʼu.
Nitorina Ọlọrun ni ko tiju lati wa ni a npe Ọlọrun wọn, nitoriti o ti pèse fun wọn a ilu. "
1.181752
14"Isin ifa biyya lafaa ti.
14"Ẹ̀yin ni ìmọ́lẹ̀ ayé.
1.181132
Horaa loo yiri: Dabkuu Munaafaq Shidaa Mu'min Baa Ku Gubta.
À íà çàõàä ì3ëàâ3öà,
1.181049
Yeroo hundaa ishii keessa kan jiraatan ta'anii tiiksas ta'ee gargaaraa [isaan baraaru] hin argatan.
Bẹni oorun ko ni lu wọn, tabi eyikeyi ooru.
1.180805
25 Isaan kun itti dabalanii, "Ati Kristos yookiis Eliyaas yookiis raaji cha ergs hin ta'inii maaliif cuuphxa ree?" jedhanii isa in gaafatan*.
Wọ́n wá bi í pé, "Kí ló dé tí o fi ń ṣe ìrìbọmi nígbà tí kì í ṣe ìwọ ni Mesaya tabi Elija tabi wolii tí à ń retí?
1.179963
Seenaa 59: Daawit Baqachuu Kan Qabu Maaliifi
Ìtàn 59: Ìdí Tí Dáfídì Fi Gbọ́dọ̀ Sá Lọ
1.179183
Raajii dubbachuun takkaa jaalala namaatin hin taane; garuu namoonni Hafuura Qulqulluudhaan geggeeffamanii, wanta Waaqayyo biraa fudhatan dubbataniiru.
Nítorí àsọtẹ́lẹ̀ kan kò ti ipa ìfẹ́ ènìyàn wá rí: ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn ńsọ̀rọ̀ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run bí a ti ńdarí wọn láti ọwọ́ Ẹ̀mí mímọ́ wá."
1.17873
Dhuga-bayiisni sunis isa kana; Waaqayyo jireenna barabaraa nuu kenneera; jireenni sunis Ilma isaa keessa jira.
Ẹ̀rí náà ni pé Ọlọrun ti fún wa ní ìyè ainipẹkun, ìyè yìí sì wà ninu Ọmọ rẹ̀.
1.178449
Urjicha yeroo arganitti gammachuu guddaadhaan garmalee gammadan.
Nígbà tí wọ́n rí ìràwọ̀ náà, inú wọn dùn gan-an.
1.178016
Dhugich in hubattu; dhugichis birmaduu isin in baasa" jedhe.
ẹ óo mọ òtítọ́, òtítọ́ yóo sì sọ yín di òmìnira.
1.177758
Qajeelinnii fi jal'inni maal walitti qabuu?
Nítorí ìrẹ́pọ̀ wo ni ó wà láàrin ìwà òdodo ati aiṣododo?
1.177713
Berri waan arki doonaa.
Emi yoo ri ọ ni ọla.
1.177688
Bara baraaf gad of deebisnee jiraachuuf maaltu nu gargaara?
Kí ló máa mú ká jẹ́ amẹ̀tọ́mọ̀wà títí láé?
1.177336
29 Barattoonni isaas akkana jedhan; "kunoo, ati ammayyuu fakkeennaan otoo hin ta'in ifatti baaftee dubbachaa jirta!
29 Awọn ọmọ-ẹhin rẹ wi fun u pe, Wo o, nisisiyi iwọ nsọrọ gbangba, iwọ kò si sọ owe.
1.177235
22 Yihudaa nama biyya Keriyot utuu hin ta'in, Yihudaa inni tokko, "Gooftaa, attamitti ati biyya lafaatti utuu hin ta'in nutti of mul'ifta ree?" ittiin jedhe*.
22 Judasi wi fun u pe, (kì iṣe Iskariotu) Oluwa, ẽhatiṣe ti iwọ ó fi ara rẹ hàn fun awa, ti kì yio si ṣe fun araiye?
1.177017
Daandii qajeelaatti nu qajeelchi.
Ó máa tọ́ wa sọ́nà tó dáa.
1.176942
.yeti suyii chhumaai taeti suyii chhumaai"
O oṣupa, iwọ kì yio si gbe si afonifoji Aijaloni!"
1.1768
Thammudu meelage ariyana kooda
Aansu tham jaaye mere
1.176375
Har'as Waaqayyo nutti dubbataa?
Njẹ́ Ọlọ́run ṣì ńbáwa sọ̀rọ̀ lónìí?
1.176289
Ha ta'uu malee kan birootiif dhiifama gochuu yoo baatan, abbaan keessa cubbuu keessan dhiifama isini hin godhu.
Ṣugbọn bí ẹ kò bá dáríjì àwọn eniyan, Baba yín kò ní dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín.
1.176063
Ergamoonni Waaqayyoo naannoo namoota Waaqayyo sodaatanii ni buufatu, isaan ni fayyisus Faar.
Angẹli OLUWA yí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀ ká,a sì máa gbà wọ́n.
1.17587
Inni/isheen duraan dursitee Waaqayyoon waan hundumaa durseeraa, jireenya isaaniitii?
Ǹjẹ́ òun ti fi Ọlọ́run ṣe àkọ́kọ́ tẹ́lẹ̀ àti àkọ́kọ́ jùlọ nínú ayé rẹ̀?
1.175293
Hase yeeshee, intooda badani ma yeeshaan raandhiis.
lọ lati ileri rẹ: ṣugbọn ọpọlọpọ awọn enia ni oye ko.
1.175
Biyya lafaafi wanta biyya lafaa jaallachuutti hinhidhiinaa jedha.
Ẹ má fẹ́ràn ayé tabi àwọn nǹkan ayé.
1.174586
14:4) Bilisummaa isaa warra kaan ittiin gargaaruuf waan itti fayyadamuuf fakkeenya gaarii nuuf taʼa!
14: 4) Ẹ ò rí i pé àpẹẹrẹ àtàtà nìyẹn tó bá di pé ká lo òmìnira tá a ní lọ́nà tó máa ṣe àwọn míì láǹfààní!
1.173846
Isinis akkasuma Waaqayyoodhaa fi horiidhaaf hojjechuu hin dandeessan" jedha.
Ẹ̀yin kò lè sin Ọlọ́run àti owó papọ̀."
1.17356
Waaʼee keenyaafi wanta itti amannu caalaatti baradhu.
Mọ púpọ̀ sí i nípa wa àtàwọn ohun tá a gbà gbọ́.
1.173458
15 Dhugaa dubbachuuf, hamma guyyaa harʼaatti, yeroo kitaabonni Musee dubbifaman hundatti garaan isaanii akkuma haguugametti jira.
3:15 Sugbon ani titi di oni, nigbati Mose ti wa ni ka, kan ibori ti wa ni ṣi ṣeto lori ọkàn wọn.
1.173405
Egaa Daawit ofii isaatii 'Gooftaa koo' jedhee erga isa waamee, attamitti immoo ilma isaa ta'a ree?" jedhe.
Nígbà tí Dafidi pè é ní Oluwa, báwo ni ó ti ṣe tún jẹ́ ọmọ rẹ̀?
1.173166
Deebii gaaffii Maariyaamiitiin, "kun akkamitti ta'uu danda'a?"
Ní ìdáhùn sí ìbéèrè Màríà, "Èyí ó ha ti ṣe rí bẹ̀?"
1.173057
Eebbahaa wuu u-fidiyaa rizqiga cidduu doono wuuna u-qaddaraa [cidhiidhiyaa cidduu doono] illeen Eebbe addoomadiisa waa oge arkee.
Óâû ìíѣ óíå áû ñú òîáîþ (Áîðèñîì) óìðåòè ìè (Ãëåáó), íåæå óåäèíåíó è óñèðåíó îò òåáå âú ñåìü æèòèè ïîæèòè.
1.172906
14"Isin ifa biyya lafaa ti.
14 Ẹnyin ni imọlẹ aiye.
1.172672
Yeroo hundaa ishii keessa kan jiraatan ta'anii tiiksas ta'ee gargaaraa [isaan baraaru] hin argatan.
Ẹyọ ẹnìkan wọn kò sì sùn,bẹ́ẹ̀ ni wọn kò tòògbé.
1.172378
Masjiida kana keessa dhiirota qofatu quraana itti qara'a.
Mimọ Koran ni awọn nikan ni ohun ti o mu ki o kan iyanu.
1.171919
22 Yihudaa nama biyya Keriyot utuu hin ta'in, Yihudaa inni tokko, "Gooftaa, attamitti ati biyya lafaatti utuu hin ta'in nutti of mul'ifta ree?" ittiin jedhe*.
22 Judasi (kì iṣe Iskariotu) wi fun u pe, Oluwa, ẽṣe ti iwọ fi n fi ara hàn fun wa, kì iṣe fun aiye?
1.171618
Isa lafa geessanii yaadaa malee; yaada keessan wanta isa lafarraa jiruuttii hinhidhiinaa.
Ẹ máa lépa àwọn ohun tí ó wà lọ́run, ẹ má lépa àwọn ohun tí ó wà láyé.
1.170215
(trg) ="3"> Namoonni kan dhiphatanii fi kan duʼan maaliifi ?
(trg) ="3"> Kí nìdí tá a fi ń jìyà tá a sì ń kú ?
1.170172
2 Iga samatabbixi xumaanfalayaasha,
2 Gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníṣẹ́ búburú
1.169627
Kana keessaa hin sodaatinaa; abbaan keessan mootummaa isaa isiniif kennuu jaallateera.
Má bẹ̀ru, agbo kekere; nitori didùn inu Baba nyin ni lati fi ijọba fun nyin.
1.16929
itti aansee dhugaa keeti jechi kee dhugaadha
Yà wọn nipasẹ otitọ rẹ: ọrọ rẹ ni otitọ.
1.16821
Raajiin Yihudaa maqaan isaa hin caqasamne tokko utuu maal hin godhin hafeera?
Kí ni wòlíì tó wá láti Júdà yẹn kò ṣe, kí ló sì yọrí sí?
1.16809
kan dabarsee natti si kenne sabuma keetii fi luboota hangafoota; garuu ati maal balleessitee ti?
Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè rẹ, àti àwọn olórí àlùfáà ni ó fà ọ́ lé èmi lọ́wọ́: kín ní ìwọ ṣe?"
1.168011
Yeroo Hunda Dursa Argachuu Barbaaddaa?
Ǹjẹ́ O Máa Ń Fẹ́ Jẹ́ Ẹni Àkọ́kọ́ Nígbà Gbogbo?
1.167884
(Maatewos 6:9) Waaqayyo maqaawwan ulfinaa hedduu qabaatuyyuu, maqaansaa garuu tokko qofadha.
(Mátíù 6:9) Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Ọlọ́run ní ọ̀pọ̀ orúkọ oyè, orúkọ kan ṣoṣo ló ní.
1.167834
dubartoota keessa kan eebbifamtedha."
Alabukun-fun ni iwọ laarin awọn obinrin. "
1.165898
Garaa kee guutuu Waaqayyoon amanadhu, hubannaa ofii keetiitti hin hirkatin!
"Fi gbogbo àyà rẹ gbẹ́kẹ̀le Olúwa; má sì ṣe tẹ̀sí ìmọ̀ ara rẹ.
1.16582
Mirga filannoo keenya matumaa maal gochuu hin qabnu?
Kí ni kò yẹ ká ṣe sí òmìnira tí Jèhófà fún wa?
1.165309
Inaa lilaahi wa inaa ilaahi raajucuun.
OLUWA fi èyí hàn yín, kí ẹ lè mọ̀ pé òun ni Ọlọrun, ati pé kò sí Ọlọrun mìíràn àfi òun nìkan.
1.165193
"Hin sodaatinaa! [...] saba hundumaaf kan ta'uu, mandara Daawititti Fayyisaan isiniif dhalateera, inni immoo kristos gooftaa dha" Lk.
Nitori a bi fun ọ loni ni ilu Dafidi ni Olugbala, ẹniti iṣe Kristi Oluwa" (Luku 2:8-11).
1.165174
27 Inni ammoo, "ani kanaan dura isinitti himeera; isinis hin dhageenye; ammas maaliif dhagawuu barbaaddu? isinis barattoota isaa ta'uu barbaadduu?"
27 O da wọn lohùn wipe, Emi ti sọ fun nyin na, ẹnyin ko si gbọ́: nitori kini ẹnyin ṣe nfẹ tún gbọ́? ẹnyin pẹlu nfẹ ṣe ọmọ-ẹhin rẹ̀ bi?
1.164607
4:24 "Waaqayyo hafuura; warri isaaf sagadanis hafuuraa fi dhugaadhaan isaaf sagaduun in ta'aaf ittiin jedhe."
24 Ẹmí li Ọlọrun: awọn ti o ba foribalẹ ki o mã sìn ni ẹmí ati otitọ.
1.16456
Allihiin taqaanniin.
Ṣugbọn kini eyi rẹ aramada idanimo ni, o ko mọ.
1.164001
Rabbiin (subhaanahu wa ta'aala) warra dhugaan amananii fi hojii gaarii hojjatan, gaddii fi dhiphinna akka isaan irra hin jirre waadaa galee jira.
4: 173 Bi fun awon ti o gbagbo ati ki o ṣe iṣẹ rere, o yoo san wọn ni kikun wọn oya, ati awọn ti o yio si mu wọn lati rẹ Eru Ojiji.
1.163995
Egaa atis aboo isaanii akka hin sodaanne godhachuu in barbaaddaa?
Njẹ iwọ ha fẹ ṣaibẹru aṣẹ wọn?
1.163595
Muuzii dhandhama isaan kan hin jaalanne jiraa?
Ko fẹran orin naa?
1.16356
(Muchi arfan aannanii);
ati pe o le fi ẹrin ti o ku han,
1.163221
Dubbiin kee miila kootiif ibsaa dha, daandii koo irrattis in ifa.
Ọ̀rọ̀ rẹ ni àtùpà fún ẹsẹ̀ mi,òun ni ìmọ́lẹ̀ sí ọ̀nà mi.
1.163206
Ogummaan jalqabaa Waaqayyoon sodaachuu akka ta'e agarsiisuuf.
Ibẹru Oluwa ni ọgbọn beginingof.
1.162684
35 Yesuusis akka isaan gadi isa baasan dhagaye; yommuu isa argettis, "ati ilma namaatti ni amantaa?
35Jesu gbọ́ pé, wọ́n ti tì í sóde; nígbà tí ó sì rí i, ó wí pe, "Ìwọ gba Ọmọ Ọlọ́run, gbọ́ bí?"
1.162654
Isaan keessaa tokkoyyuu fedhii Abbaa keessanii malee lafa hin buutu.
Sibẹ ọ̀kan ninu wọn kò lè jábọ́ sílẹ̀ lẹ́yìn Baba yín.
1.162586
(trg) ="33"> Kanaaf , wanta dabalataa barachuun barbaade . " - Deeniiz , Meeksikoo .
(trg) ="35"> Èyí mú kó wù mí láti mọ̀ sí i . " - Dennize , Mẹ́síkò .
1.162548
Utuu ana beektaniittu taʼee, Abbaa koos ni beektu turtan" jedhee deebiseef.
Ti o ba mọ mi, boya o yoo mọ Baba mi pẹlu. "
1.162346
Kiristaana lammffaa dhalate ta'uu jechuun maal jechuudhaa?
Kí Ló Túmọ̀ Sí Láti Di Àtúnbí?
End of preview. Expand in Data Studio

Oromo-Yoruba_Sentence-Pairs Dataset

This dataset contains sentence pairs for African languages along with similarity scores. It can be used for machine translation, sentence alignment, or other natural language processing tasks.

This dataset is based on the NLLBv1 dataset, published on OPUS under an open-source initiative led by META. You can find more information here: OPUS - NLLB-v1

Metadata

  • File Name: Oromo-Yoruba_Sentence-Pairs
  • Number of Rows: 84299
  • Number of Columns: 3
  • Columns: score, Oromo, Yoruba

Dataset Description

The dataset contains sentence pairs in African languages with an associated similarity score. Each row consists of three columns:

  1. score: The similarity score between the two sentences (range from 0 to 1).
  2. Oromo: The first sentence in the pair (language 1).
  3. Yoruba: The second sentence in the pair (language 2).

This dataset is intended for use in training and evaluating machine learning models for tasks like translation, sentence similarity, and cross-lingual transfer learning.

References

Below are papers related to how the data was collected and used in various multilingual and cross-lingual applications:

[1] Holger Schwenk and Matthijs Douze, Learning Joint Multilingual Sentence Representations with Neural Machine Translation, ACL workshop on Representation Learning for NLP, 2017

[2] Holger Schwenk and Xian Li, A Corpus for Multilingual Document Classification in Eight Languages, LREC, pages 3548-3551, 2018.

[3] Holger Schwenk, Filtering and Mining Parallel Data in a Joint Multilingual Space ACL, July 2018

[4] Alexis Conneau, Guillaume Lample, Ruty Rinott, Adina Williams, Samuel R. Bowman, Holger Schwenk and Veselin Stoyanov, XNLI: Cross-lingual Sentence Understanding through Inference, EMNLP, 2018.

[5] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Margin-based Parallel Corpus Mining with Multilingual Sentence Embeddings arXiv, Nov 3 2018.

[6] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Massively Multilingual Sentence Embeddings for Zero-Shot Cross-Lingual Transfer and Beyond arXiv, Dec 26 2018.

[7] Holger Schwenk, Vishrav Chaudhary, Shuo Sun, Hongyu Gong and Paco Guzman, WikiMatrix: Mining 135M Parallel Sentences in 1620 Language Pairs from Wikipedia arXiv, July 11 2019.

[8] Holger Schwenk, Guillaume Wenzek, Sergey Edunov, Edouard Grave and Armand Joulin CCMatrix: Mining Billions of High-Quality Parallel Sentences on the WEB

[9] Paul-Ambroise Duquenne, Hongyu Gong, Holger Schwenk, Multimodal and Multilingual Embeddings for Large-Scale Speech Mining, NeurIPS 2021, pages 15748-15761.

[10] Kevin Heffernan, Onur Celebi, and Holger Schwenk, Bitext Mining Using Distilled Sentence Representations for Low-Resource Languages

Downloads last month
16

Collection including michsethowusu/oromo-yoruba_sentence-pairs